Patrice Tlhopane Motsepe (tí a bí ní ọjọ́ kàndínlọ́gbọ̀n oṣù Kínní ọdún 1962) jẹ́ biloníà ọmọ orílẹ̀ èdè South Africa.[2] Ní oṣù kẹta ọdún 2021, ó di ààrẹ Confederation of African Football.[3] Òun ni olùdásílẹ̀ àti adarí African Rainbow Minerals. Ó wà ní ipò adarí ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé iṣẹ́, àwọn ilé iṣẹ́ bi Harmony Gold, Sanlam.[4] àti World Economic Forum.[5]

Patrice Motsepe
Motsepe ní ọdún 2009
7th President of CAF
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
12 March 2021
AsíwájúAhmad Ahmad
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Patrice Tlhopane Motsepe

28 Oṣù Kínní 1962 (1962-01-28) (ọmọ ọdún 62)
Orlando West, Soweto, Johannesburg.
(Àwọn) olólùfẹ́
Precious Moloi (m. 1989)
Àwọn ọmọ3[1]
RelativesTshepo Motsepe (sister)
Bridgette Radebe (sister)
Cyril Ramaphosa (brother-in-law)
Jeff Radebe (brother-in-law)
Alma materUniversity of Swaziland
University of the Witwatersrand
OccupationPhilanthropist, Advocate
Known forFounder, African Rainbow Minerals

Ní ọdún 2003, ó ra ẹgbẹ́ agbábọ́ọ́lù Mamelodi Sundowns.[6]

Ní 2013, ó ṣe ipinu láti fi idà ṣíméjì owó fún ríran àwọn aláìní lọ́wọ́.[7]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Who Are Patrice Motsepe's Children Thlopie, Kgosi and Kabelo?". Retrieved 24 May 2023. 
  2. "South African tycoon Motsepe elected as African football supremo". RFI (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-03-12. Retrieved 2024-01-05. 
  3. "Patrice Motsepe: Africa's ninth richest person appointed Caf president | Goal.com". www.goal.com. Retrieved 2021-03-12. 
  4. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named whoswho
  5. "Leadership and Governance - World Economic Forum". 
  6. "Patrice Motsepe's lack of success at Mamelodi Sundowns". Kick Off. 20 August 2013. Archived from the original on 11 August 2018. Retrieved 11 August 2018. 
  7. "Patrice Motsepe: South African tycoon to donate millions". BBC News. 30 January 2013. https://www.bbc.co.uk/news/world-africa-21259399.