Patricia Ofori jẹ agbabọọ̀lu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ kẹsan, óṣu June ni ọdun 1981 ti o si ku ni ọjọ 20, óṣu April ni ọdun 2011. Agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi defender.

Patricia Ofori
Personal information
Ọjọ́ ìbí(1981-06-09)9 Oṣù Kẹfà 1981
Ibi ọjọ́ibíGhana
Ọjọ́ aláìsí20 April 2011(2011-04-20) (ọmọ ọdún 29)
Ibi ọjọ́aláìsíHuntsville, Alabama
Ìga1.70m
Playing positionDefender (association football)
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2001–2004Mawuena Ladies
National team
2003–2007Ghana women's national football team8(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Àṣeyọri

àtúnṣe
  • Patricia kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ti ọdun 2003 ati 2007.

Itọkasi

àtúnṣe