Paul Biyoghé Mba (ojoibi 18 April 1953[1]) je oloselu ara Gabon to je Alakoso Agba ile Gabon lati July 2009. O je omo egbe Gabonese Democratic Party (PDG), o ti wa nipo alakoso ninu ijoba ko to di pe won yan gege bi Alakoso Agba.

Paul Biyoghé Mba
Alakoso Agba ile Gabon
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
17 Osu Keje 2009
ÀàrẹRose Francine Rogombé (Adipo)
Ali Bongo Ondimba
AsíwájúJean Eyeghe Ndong
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí18 Oṣù Kẹrin 1953 (1953-04-18) (ọmọ ọdún 71)
Donguila, French Equatorial Africa (oni bi Gabon)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPDG
  1. "Gabon : Paul Biyoghe Mba nouveau Premier ministre" Archived 2009-07-19 at the Wayback Machine., GabonEco, 17 July 2009 (Faransé).