Paul Adrien Maurice Dirac, OM, FRS (pípè /dɪˈræk/ di-RAK; 8 August 1902 – 20 October 1984) je onimofisiiki oniro ara Britani. Dirac se afikun pataki si ibere isise ero ayosere ati agbaraonina ayosere. O di ipo Ojogbon Aga Lukas fun Mathematiiki mu ni Yunifasiti ilu Cambridge, o si lo odun merinla togbeyin laye re ni Florida State University.

Paul Adrien Maurice Dirac
ÌbíPaul Adrien Maurice Dirac
(1902-08-08)8 Oṣù Kẹjọ 1902
Bristol, England
Aláìsí20 October 1984(1984-10-20) (ọmọ ọdún 82)
Tallahassee, Florida, USA
Ọmọ orílẹ̀-èdèUnited Kingdom
PápáPhysics
Ilé-ẹ̀kọ́Cambridge University
Florida State University
Ibi ẹ̀kọ́University of Bristol
Cambridge University
Doctoral advisorRalph Fowler
Doctoral studentsHomi Bhabha
Harish Chandra Mehrotra
Dennis Sciama
Behram Kurşunoğlu
John Polkinghorne
Ó gbajúmọ̀ fúnDirac equation
Dirac comb
Dirac delta function
Fermi–Dirac statistics
Dirac sea
Dirac spinor
Dirac measure
Bra-ket notation
Dirac adjoint
Dirac large numbers hypothesis
Dirac fermion
Dirac string
Dirac algebra
Dirac operator
Abraham-Lorentz-Dirac force
Dirac bracket
Fermi–Dirac integral
Negative probability
Dirac Picture
Dirac-Coulomb-Breit Equation
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síNobel Prize in Physics (1933)
Religious stanceAtheist [1]
Notes
He is the stepfather of Gabriel Andrew Dirac.

Ninu awon awari re, o sagbekale isodogba Dirac, eyi salaye iwuwa awon fermion eyi lo si faye gba isotele wiwa olodi elo.

Dirac pin Ebun Nobel ninu Fisiksi fun 1933 pelu Erwin Schrödinger, "fun sisawari awon iru iro atomu tuntun to wulo."[2]

Igba ewe

àtúnṣe

Paul Dirac je bibi ni ilu Bristol,[3] Ilegeesi, ni adugbo Bishopston lo gbe dagba.


  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named religion
  2. "The Nobel Prize in Physics 1933". The Nobel Foundation. Retrieved 2007-11-24. 
  3. Register of births at Family Records Office

Iwe kika lekunrere

àtúnṣe

Ijapo Interneti

àtúnṣe
 
Wikiquote logo
Nínú Wikiquote a ó rí ọ̀rọ̀ tójẹmọ́: