Paul Hermann Müller bakanna bi Pauly Mueller (12 Oṣù Kínní 1899 – October 12, 1965) je omo Swiss aseogun ati elebun Nobel. Ni 1948 o gba Ebun Nobel fun Iwosan fun iwari re ni 1939 pe DDT se lo bi ogun kokoro ati kikojanu awon arun vector bi malaria ati iba iponju.[1] [2]

Paul Hermann Müller
ÌbíJanuary 12, 1899
Olten, Solothurn, Switzerland
Aláìsí12 October 1965(1965-10-12) (ọmọ ọdún 66)
Basel, Switzerland
Ọmọ orílẹ̀-èdèSwiss
PápáChemistry
Ilé-ẹ̀kọ́J. R. Geigy AG
Ibi ẹ̀kọ́Universität Basel
Ó gbajúmọ̀ fúnInsecticidal applications of DDT
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síNobel Prize in Physiology or Medicine (1948)


Awon Itoka si

àtúnṣe
  1. "Paul Müller - Biographical". Nobelprize.org. 2014-05-21. Retrieved 2018-07-16. 
  2. "Who is Paul Hermann Müller? Everything You Need to Know". Paul Hermann Müller Biography. 1925-05-25. Retrieved 2018-07-16.