Paul Moukila
Paul Moukila jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ẹlẹ́sẹ̀ ọmọ orílẹ̀ èdè Congo tí ó gba àmì ẹ̀yẹ ẹni tí ó mọ bọ́ọ̀lù gbá jù ní Áfríkà ní Ọdún 1979.[1]
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Paul "Sayal" Moukila | ||
Ọjọ́ ìbí | 6 Oṣù Kẹfà 1950 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Souanké, Middle Congo | ||
Ọjọ́ aláìsí | 24 May 1992 | (ọmọ ọdún 41)||
Ibi ọjọ́aláìsí | Meaux, France | ||
Playing position | Forward | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
1971–1975 | CARA Brazzaville | ||
1975–1976 | Strasbourg | 4 | (1) |
1976–1978 | CARA Brazzaville | ||
National team | |||
1971–1978 | Republic of the Congo national team | 13 | (2) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọ́n Itọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Ayelo, Jean Bruno (11 January 2011). "Moukila Paul (Sayal), Ballon d'or africain '74: Le footballeur qui a marqué tout le cinquantenaire du Congo" (in French). Mbokamosika.