Paul Reynaud (tí a bí ní 15 October 1878 ti o si fi ayé sílè lojo 21 September 1966)  je olósèlú àti  Alakoso Agba ile Furansi tele. Òpòlopò mo fún ija fun ominira ètò òrò ajé àti ija tako orílè-èdè Germini. Paul jé alakoso agba ti orílè-èdè Furansi nigba tí orílè-èdè Germini doju ogun ko Furansi ni odun 1940, gbogbo ipa rè láti gba Furansi lówó Germini já sofo koto dipé ó kowe fipo rè sílè ní June 1940.[1] O gbiyanju láti sá kuro ni Furansi sugbon o kuna koto dipe awon omo ologun Philippe Pétain gbamú. A jú sewon ní ní orílè-èdè Germini ni odun 1942, o tún sewon ní orílè-èdè Australia koto dipé a tu sílé ni odún 1945 léyìn ogun Itter Castle.[2]

Paul Reynaud


Igbe-aye rè àti ipa rè nínú oselu

àtúnṣe

Abí Reynaud sí Barcelonnette, Alpes-de-Haute-Provence, orúko baba àti ìyá rè ni Alexandre Reynord àti Amelie Reynord(orúko baba Amelie ni Gassier). Reynaud kó nipa ìmò-òfin ní ilé-ìwé Sorbonne. Léyìn to keko gboyè ní ilé-ìwé Sorbonne, Reynaud wo inú oselu.[3]

Àwọn Itokasi

àtúnṣe
  1. "Paul Reynaud". Encyclopedia Britannica. 2021-10-11. Retrieved 2022-07-18. 
  2. Roberts, Andrew (2018-10-01). "World War II’s Strangest Battle: When Americans and Germans Fought Together". The Daily Beast. Retrieved 2022-07-18. 
  3. "Paul Reynaud". Military Wiki. 2022-07-06. Retrieved 2022-07-18.