Paulinus Igwe Nwagu

Olóṣèlú

Paulinus Igwe Nwagu, ti a bi ni ọjọ kejila, oṣu kẹfa ọdun 1959 jẹ ọkan lara awọn oloṣelu ni orilẹ-ede Nàíjíríà. O ti jẹ aṣoju fun Ẹkun Ariwa Ezza ati Ishielu Ipinlẹ Ebonyi, ni orilẹ-ede Nàíjíríà ni ile igbimo aṣofin kekere. Ninu ibo ti a di ni orilẹ-ede Nàíjíríà ni oṣù kẹrin ọdún 2011, Paulinus Igwe Nwagu dije, o si wọlé gẹ́gẹ́ bíi ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà lábẹ́ àsìá Ẹgbẹ́ PDP.

Paulinus Igwe Nwagu