Haufiku Paulus Hamutenya (tí wọ́n bí ní c. 1884, Oukwanyama, Angola — tí ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹwàá ọdún 1932[1]) jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹni méje àkọ́kọ́ tí Matti Tarkkanen yàn láti jẹ́ olùsọ àgùntàn ní Oniipa, Ovamboland, ní ọdún 1925.[2]

Hamutenya jẹ́ ọmọ Hamutenya gwaNghililewanga àti Ndayapi yaKavengula. A bi sí Onandjokwe ní c. 1884, a sì ṣe ìrìbọmi rẹ̀ ní ìlú kan náà ní ọdún 1919.[1]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 Nambala, Shekutaamba V. V. (1995). Ondjokonona yaasita naateolohi muELCIN 1925–1992. Oniipa, Namibia: ELCIN. p. 81. 
  2. Peltola 1958, p. 212.