Pearlena Igbokwe
Pearlena Igbokwe ni olórí ni Universal Television èyí tí ó jé ẹ̀yà kan lára NBC Universal Television Group.[1][2] Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó wá láti Áfríkà tí ó má se olórí fún ilé iṣẹ́ telefisionu ni orile-ede United States of America. Ó jẹ́ ọmọ ẹ̀yà igbo ni Nàìjíríà.
Pearlena Igbokwe | |
---|---|
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | journalist |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeWọn bíi Igbokwe ni ìpínlè Èkó ni Nàìjíríà ni ìgbà 1960. Ó lọ sí orile-ede USA ni ìgbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́fà.[3] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Yale University àti Columbia University.[4]
Iṣẹ́
àtúnṣeIgbokwe bẹẹ rẹ̀ iṣẹ́ idaraya ni Showtime. Ó ṣe adari fún àwọn eré bii Nurse Jackie, The Big C àti Master of sex. Ní ọdún 2012, wọn fi Igbokwe jẹ́ igbá kejì adarí fún idagbasoke eré ni NBC.[5] Ó ṣe adari fún àwọn ère bíi The blacklist, Blindspot, Chicago Med, Shades of blue, This is us, Timeless àti Taken. Ní ọdún 2016, wọn fí jẹ alákòóso fún Universal Television, èyí tí ó fi jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ láti ilẹ̀ Áfríkà tí ó má jẹ́ alákòóso fun ilé iṣẹ́ telefisionu ni USA.[6] Ní ọdún 2018, Igbokwe dára pọ̀ mọ́ àwọn adari fún HRTS.[7][8] Ní ọdún náà ni ó dára pọ̀ mọ́ NAPTE.[9]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ James, Meg (June 3, 2016). "NBC's Pearlena Igbokwe named president of Universal TV". Los Angeles Times. Retrieved May 14, 2017.
- ↑ Holloway, Daniel (2016-06-03). "Pearlena Igbokwe Named President of Universal Television" (in en-US). Variety. https://variety.com/2016/tv/news/pearlena-igbokwe-president-universal-television-1201788508/.
- ↑ "Pealena Igbokwe". Archived from the original on January 14, 2018. https://web.archive.org/web/20180114020903/http://ladybrillemag.com/exclusive-interview-pearlena-igbokwe-us-television-executive-is-ladybrille-woman-of-the-month/. Retrieved January 13, 2018.
- ↑ Max Ndianafo (August 13, 2016). "20 Facts on US based Pearlena Igbokwe as she records a 1st in US TV Network". CP Africa. Archived from the original on April 5, 2019. https://web.archive.org/web/20190405025053/https://www.cp-africa.com/2016/08/13/nigeria-10-facts-on-us-based-pearlena-igbokwe-as-she-records-a-1st-in-us-tv-network/.
- ↑ Goldberg, Lesley (July 10, 2012). "NBC Names Pearlena Igbokwe New Drama Head". The Hollywood Reporter (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved May 14, 2017.
- ↑ David, Adetula (June 6, 2016). "Meet Pearlena Igbokwe, the first Nigerian woman to head a major US television network - Ventures Africa" (in en-US). Ventures Africa. http://venturesafrica.com/what-you-need-to-know-about-pearlena-igbokwe-first-nigerian-to-head-a-major-us-television/.
- ↑ "Hollywood Reporter: Pearlena Igbokwe, Dan Erlij Among New HRTS Board Members".
- ↑ "Deadline: HRTS Elects New Officers From WME, Universal, Lionsgate, City National Bank".
- ↑ "NATPE: NATPE ADDS NETFLIX VP ORIGINAL CONTENT CINDY HOLLAND, FACEBOOK HEAD OF DEVELOPMENT MINA LEFEVRE, UNIVERSAL TELEVISION PRESIDENT PEARLENA IGBOKWE AND CBS SVP ALTERNATIVE PROGRAMMING SHARON VUONG TO ITS BOARD". Archived from the original on 2020-09-20. Retrieved 2020-05-13.