Perpetua Nkwocha
Agbaọ́ọ̀lù ọmọ orílé-éde Nàìjíríà
Perpetua Nkwocha jẹ ọkan lára àwọn agbábọ́ọ̀lú-ẹlẹ́sẹ̀ lóbìnrin tí a bíní ọjọ́ kẹta, oṣù kínní odún 1976. Arábìnrin náà ṣeré tẹ́lẹ̀ rí fún Swedish club Sunnanå SK àtipé agbábọ́ọ̀lú náà jẹ́ captain tẹ́lẹ̀ rí fún team àpapọ àwọn obìnrin ilẹ̀ Nàìjíríà lórí bọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀[1][2][3].
Àṣeyọri
àtúnṣeItọkasi
àtúnṣe- ↑ https://www.eurosport.com/football/perpetua-nkwocha_prs281835/person.shtml
- ↑ https://fbref.com/en/players/b4945edc/Perpetua-Nkwocha
- ↑ https://sportsbrief.com/football/super-falcons/17140-asisat-oshoala-picks-snubs-mercy-akide-selects-super-falcons-icon-perpetua-nkwocha-lead-5-aside-dream-team/
- ↑ https://www.goal.com/en-ng/news/4093/nigerian-football/2012/10/24/3473703/perpetua-nkwocha-sets-15-goal-target-for-african-women
- ↑ https://www.goal.com/en-ng/news/12072/nigeria-women/2015/05/21/11935672/super-falcons-land-in-canada-with-perpetua-nkwocha-for-world
- ↑ https://www.thecable.ng/golden-oldie-nkwocha-makes-world-cup-team/amp