Peso Argẹntínà jẹ́ owóníná ní orílẹ̀ èdè Argẹntínà pẹ̀lú àmì ìdánimọ $ tí ó máa n wà lẹ́yìn iye owó bí ó ṣe wà fún àwọn ìlú tókù tó ń lo owó dólà. Ó pín sí ọnà ọgọ́òrún. Kóòdù ISO 4217 ẹ̀ jẹ́ ARS. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ owóníná ilẹ̀̀ Argẹntínà tí wọ́n tí ná kọjá ni woṇ́n ti pè ní "peso".

Peso Argẹntínà
Peso Argẹntínà
Peso argentino  (Spanish)
ISO 4217 code ARS
Central bank Central Bank of the Republic of Argentina
Website [http://bcra.gov.ar bcra.gov.ar]
User(s)  Argentina
Inflation 26 % estimated (2015)
Source Banco Ciudad and private consultants[1][2]

Official figures are substantially inferior.[3]

Subunit
1/100 centavo
Symbol $
Coins 5, 10, 25, 50 centavos, 1 peso, 2 pesos
Banknotes 2, 5, 10, 20, 50, 100 pesos

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe