Philicity Asuako
Philicity Asuako jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 25, óṣu December ni ọdun 1999. Agbabọọlu naa ṣere fun Thunder Queens F.C gẹgẹ̀bi defender[1].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 25 Oṣù Kejìlá 1999 | ||
Playing position | Defender | ||
Club information | |||
Current club | Police FC | ||
Number | 2 | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Thunder Queens F.C. | |||
Police Ladies F.C. (Ghana) | |||
National team‡ | |||
2018 | Ghana women's national football team | 1 | (0) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àṣeyọri
àtúnṣe- Philicity kopa ninu Nations Cup awọn obinrin ilẹ afirica ti ọdun 2018[2].