Philip Seymour Hoffman

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Philip Seymour Hoffman (ojoibi July 23, 1967) je osere ati oludari filmu ara Amerika to gba Ẹ̀bùn Akádẹ́mì fún Òṣeré Okùnrin Dídárajùlọ. Hoffman bere isere lori telifisan ni 1991, lodun to tele o bere sini kopa ninu filmu. O bere sini gbajumo diedie fun isere itinleyin re ninu awon filmu bi Scent of a Woman (1992), Twister (1996), Boogie Nights (1997), The Big Lebowski (1998), Magnolia (1999), The Talented Mr. Ripley (1999), Almost Famous (2000), 25th Hour (2002), Cold Mountain (2003), Along Came Polly (2004), ati Mission: Impossible III (2006).

Philip Seymour Hoffman
Hoffman in October 2011
Ọjọ́ìbí23 Oṣù Keje 1967 (1967-07-23) (ọmọ ọdún 57)
Fairport, New York, U.S.
Iṣẹ́Actor, director
Ìgbà iṣẹ́1991–present
Alábàálòpọ̀Mimi O'Donnell (1999–present)