Phoebe Ebimiekumo
Agbaọ́ọ̀lù ọmọ orílé-éde Nàìjíríà
Phoebe Ebimiekumo (tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹtàdínlógún oṣù kìíní, ọdún 1974) jẹ́ obìnrin àgbábọ́ọ̀lù orílé èdè Nàìjíríà tó gbá bọ́ọ̀lù gẹ́gẹ́ bí dìfẹ́ńdà fún Nàìjíríà. Ó wà lára àwọn ẹgbẹ́ tí wọ́n wà ní àjọyọ̀ ìdíje fífà tí ọdún 1991 àti 1995 (1991 FIFA Women's World Cup àti 1995 FIFA Women's World Cup).[1][2][3].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 17 Oṣù Kínní 1974 | ||
Playing position | Defender | ||
National team‡ | |||
Nigeria women's national football team | |||
† Appearances (Goals). ‡ National team caps and goals correct as of 5 June 1995 (before the 1995 FIFA Women's World Cup) |
Aṣeyọri
àtúnṣe- Phoee Ebimiekumo kópa nínu ìdíje FÍFÀ a
àwọn obìnrin láàgbáyé ní ọdún 1991 ati 1995[4].