Ìṣí ojúewé ètò àkọ́kọ́
Ti idamita iyipo kan ba je 1, iyika re yio je π

Pi tabi π (tabi Pai) je ikan ninu nomba aiye imo mathematiki to se pataki. O fe to 3.14159. O duro fun ipin iyika obirikiti mo ilaidameji re.


ItokasiÀtúnṣe