Pierre Claver Maganga Moussavou

Igbá-kejì Ààrẹ ti ìlú Gabon láti ọdún 2017 wọ 2019

Pierre Claver Maganga Moussavou (tí a bí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹrin ọdún 1952[1]) jẹ́ olóṣèlú ọmọ òrílẹ̀ ède Gabon, òun ni ó jẹ́ igbá kejì Ààrẹ Gabon láti ọdún 2017 sí 2019. Òun ni Ààrẹ Social Democratic Party.

Pierre Claver Maganga Moussavou
5th Vice President of Gabon
In office
21 August 2017 – 21 May 2019
ÀàrẹAli Bongo Ondimba
AsíwájúDidjob Divungi Di Ndinge (2009)
Arọ́pòRose Christiane Raponda (2023)
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí8 Oṣù Kẹrin 1952 (1952-04-08) (ọmọ ọdún 72)
Mouila, French Equatorial Africa (present day Gabon)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúSocial Democratic Party
Alma materNational University of Gabon
University of Rennes
University of Paris

Ìpìlẹ̀ rẹ̀

àtúnṣe

A bí sínú ìdílé Punu[2]Mouila, Maganga Moussavou kó nípa ìmọ̀ ìtàn ọrọ̀ ajé ní Yunifásítì orílẹ̀ ède Gabon, àti ní Yunifásítì Rennes. Ó kàwé gba àmì ẹyẹ Dókítà ní ilé ìwé Sorbonne ní orílẹ̀ èdè Fransi. Ó padà sí Gabon ní ọdún 1978.[3]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. David E. Gardinier, Historical Dictionary of Gabon, p.466
  2. Franck Salin, "Pierre Claver Maganga Moussavou: "I am afraid for Gabon"", Afrik.com, 17 August 2009.
  3. "Election présidentielle au Gabon: Liste des candidats et leurs profils", Cameroun Link Àdàkọ:In lang