Pierre Nkurunziza

Pierre Nkurunziza (ìpè Faransé: ​[pjɛʁ n̪kyʁœ̃ziza]; 18 December 1964 – 8 June 2020) jẹ́ olóṣèlú àti Ààrẹ ilẹ̀ Bùrúndì láti ọdún 2005 títí di ìgbà tó ṣe aláìsí ní ọdún 2020.


Pierre Nkurunziza
President Nkurunziza of Burundi (6920275109) (cropped).jpg
8th President of Burundi
In office
26 August 2005 – 8 June 2020
AsíwájúDomitien Ndayizeye
Arọ́pòPascal Nyabenda (Acting)
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1964-12-18)18 Oṣù Kejìlá 1964
Bujumbura, Burundi
Aláìsí8 June 2020(2020-06-08) (ọmọ ọdún 55)
Karuzi, Burundi[1]
Ẹgbẹ́ olóṣèlúCNDD–FDD
(Àwọn) olólùfẹ́Denise Bucumi
Àwọn ọmọ6
Alma materUniversity of Burundi
Signature
WebsiteOfficial Website
ItokasiÀtúnṣe