Àdàkọ:Other uses

Taxonomy not available for Ananas; please create it automated assistant
Pineapple
A pineapple on its parent plant
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Irú:
Ìfúnlórúkọ méjì
Template:Taxonomy/AnanasAnanas comosus
Synonyms[1]

Ope oyinbo[2][3] (Ananas comosus) je eso ti o se je ; o sí je eso ti o ni iwulo pataki julo ninu idileBromeliaceae.[4]

Ọpẹ oyinbo je eso ti o tan mo awon south Amerika nitori wipe ibi yìí ni a ti n gbin lati ojo to ti pe wa. Ifarahan ọpẹ òyìnbó sì euroopu ni ọdún jeki o je ohun asa ti o se pataki julo. Lati odun 1820s ni ọpẹ òyìnbó ti je ohun ogbin ti o se gbin ni ilẹ alawọ ewe ti òyìnbó pe ni greenhouse ati ni ile ti a tile gbin nnkan.


O

Ọpẹ òyìnbó je èsó ti ki ga pupo,ododo ori rẹ ma n parapọ̀ lati di eso rẹpẹtẹ. Ohun ogbin yi máan so lori eso re Abi lati Egbe ,o sí ti maan dagba fún jíjẹ láàrin ọdún kàn.



[2][5].[5][6]

Awọn Atokasi

àtúnṣe
  1. "The Plant List: A Working List of All Plant Species". Archived from the original on 23 July 2021. Retrieved 25 July 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. 2.0 2.1 Morton, Julia F (1987). "Pineapple, Ananas comosus". Retrieved 22 April 2011. 
  3. "Pineapple Definition | Definition of Pineapple at Dictionary.com". Dictionary.reference.com. Retrieved 6 December 2009. 
  4. Coppens d'Eeckenbrugge, G; Leal, F. (2003). "Chapter 2: Morphology, Anatomy, and Taxonomy". In Bartholomew, DP; Paull, RE; Rohrbach, KG. The Pineapple: Botany, Production, and Uses. Wallingford, UK: CABI Publishing. p. 21. ISBN 978-0-85199-503-8. 
  5. 5.0 5.1 "How to grow a pineapple in your home". Pineapple Working Group-International Horticultural Society. Retrieved 15 August 2010. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  6. "Pineapple Growing". Tropical Permaculture.com (Birgit Bradtke). Archived from the original on 17 June 2010. Retrieved 15 August 2010.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)