Plantain mosa
Plantain mosa jẹ́ ohun ìpanu tí Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó sì dàbí ohun tí a mọ̀ sí small chops. E yí tí ó dàbí rẹ̀ ni wọ̀nyí grilled chicken, spring roll, samosa àti puff puff.[1]
Mosa fẹ́ dàbí Ghanaian Tatale à fi èyí tí a fi ọ̀gẹ̀dẹ̀ tó ti pọ́n jù ṣè tàbí ẹyin, fúláwà àti èyí tí a fi ọ̀gẹ̀dẹ̀ tòun tìkára rẹ̀ ṣe, atalẹ àti èròjà aládùn. Pọpọ́fùù àti Mosa fẹ́ jọra yàtọ̀ sí Mosa tí ó ní òórùn ọ̀gẹ̀dẹ̀.[2][3]
Àwọn èròjà yòókù tí a fi ń se plantain Mosa ni wọ̀nyí alùbọ́sà, òróró, bonnet pepper àti yeast. Dín Ọ̀gẹ̀dẹ̀ lílọ̀ náà títí yóò fi di búráwùn pẹ̀lú èròjà yòókù A lè fi Mosa ṣe oúnjẹ òwúrọ̀ nílé wa.[4]
See also
àtúnṣeNigeria cuisine
True Plantain
Snack
Àwọn Ìtọ́kasi
àtúnṣe- ↑ "6 delicious reasons why plantain is a culinary breakthrough". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-02-08. Retrieved 2022-06-27.
- ↑ "How To Prepare Plantain Mosa". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-04-01. Archived from the original on 2022-06-27. Retrieved 2022-06-27.
- ↑ Onyeakagbu, Adaobi (2018-09-27). "Ghanaian Tatale meets Nigerian plantain mosa". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-27.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Three recipes using overripe plantain". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-03-10. Retrieved 2022-06-27.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]