Ìṣèlú ilẹ̀ Gámbíà

(Àtúnjúwe láti Politics of the Gambia)

Ìṣèlú ilẹ̀ Gámbíà únwáyé lórí àgbékalẹ̀ ààrẹ orílẹ̀-èdè olómìnira, ní bi tí Ààrẹ ilẹ̀ Gámbíà jẹ́ olórí orílẹ̀-èdè àti olórí ìjọba, lábẹ́ sístẹ́mù ẹgbẹ́ olóṣèlú púpọ̀. Agbára aláṣe wà lọ́wọ́ ìjọba. Agbára aṣòfin wà lọ́wọ́ ìjọba àti lọ́wọ́ ilé-aṣòfin.