Ìṣúpọ̀ olùgbé

(Àtúnjúwe láti Population density)

Ìṣúpọ̀ olùgbé je iye olùgbé ninu eyo aala kan tabi ninu eyo itobi kan. O je mimu lo fun awon ohun elemi, agaga awon fun eniyan. O je oro pataki ninu jeagrafi.

Population density (people per km2) by country, 2006
Population density (people per km2) map of the world in 1994.Itokasi àtúnṣe