Pròkáríọ́tì (pípè /proʊˈkæri.oʊts/ tàbí /proʊˈkæriəts/) ni àdìpọ̀ àwọn ohun ẹlẹ́ẹ̀mí tí wọn kò ní kóróonú àhámọ́ (= karyon), tàbí àwọn apáinúmẹ́mbránì yí ká míràn. Àwọn ohun ẹlẹ́ẹ̀mí tí àhámọ́ wọ́n ní kóróonú ni à únpè ní eukaryotes. Ọ̀pọ̀ àwọn Most pròkáríọ́tì jẹ́ oníàhámọ́kan, sùgbọ́n àwọn díẹ̀ bí i àwọn miksobaktéríà ní ìpele oníàhámọ́púpọ̀ nínú ìṣe ayé wọn.[1]

Àdìmú ahamo bakteria, agbejo kan ninu meji igbesiaye prokarioti.




  1. Kaiser D (October 2003). "Coupling cell movement to multicellular development in myxobacteria". Nat. Rev. Microbiol. 1 (1): 45–54. doi:10.1038/nrmicro733. PMID 15040179.