Precious Dede ti a bini 18, óṣu January ni ọ̀dun 1980 jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ Naigiria ti o si ti ṣiwọ ìṣe. Goalkeeper naa ti ṣiṣẹ fun óriṣirìṣi club bi Delta Queens, FC Ibom Queens and Arna-Bjorna[1]

Precious Dede
Personal information
OrúkọPrecious Uzoaru Dede
Ọjọ́ ìbí18 Oṣù Kínní 1980 (1980-01-18) (ọmọ ọdún 44)
Playing positionGoalkeeper
Club information
Current clubIbom Queens
2009Arna-Bjørnar16(0)
2010–??Delta Queens
Ibom Queens
National team
YearsTeamApps(Gls)
–2016Nigeria women's national football team99(0)
† Appearances (Goals).
‡ National team caps and goals correct as of 15:46, 17 June 2015 (UTC)

Aṣeyọri

àtúnṣe
  • Dede ti kopa ninu Cup idije Awọn obinrin Agbaye ni ọdun 2003, 2007, 2011 ati 2015[2].
  • Arabinrin naa ti kopa ninu idije awọn obirin ilẹ afirica lẹ̀ẹmeji ni ọdun 2010 ati 2014[3].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://ng.soccerway.com/players/precious-dede/19445/
  2. https://www.goal.com/en/news/1656/nigeria/2011/06/14/2532159/precious-dede-to-lead-nigeria-at-womens-world-cup
  3. https://www.brila.net/precious-dede-appointed-as-india-u-17-womens-team-goalkeeper-coach/