Prisca Emeafu
Prisca Emeafu jẹ̀ Àgbààbọọlu lobinrin órilẹ ede Naigiria ti a bini 30, óṣu March ni ọdun 1972. Arabinrin na ṣere gẹgẹbi Defender fun team awọn obinrin naigiria ti national lori bọọlu[1].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 30 Oṣù Kẹta 1972 | ||
Playing position | Defender | ||
National team‡ | |||
Nigeria women's national football team | |||
† Appearances (Goals). ‡ National team caps and goals correct as of 19 June 1999 (before the 1999 FIFA Women's World Cup) |
Àṣeyọri
àtúnṣe- Prisca jẹ ọkan lara awọn elere to kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agabaye ni ọdun 1995 ati 1999[2].