Priscilla Abey (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kejìlá ọdún 1999) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n ti orílẹ̀-èdè Uganda, tó ń gbá bọ́ọ̀lù náà fún Uganda women's National team.[3]

Priscilla Abey
UTEP Miners
Forward[1]
Personal information
Born22 December 1999
Kampala, Uganda[2]
NationalityUgandan
Listed height6 ft 0 in (1.83 m)

Iṣẹ́ rẹ̀ ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga

àtúnṣe

Gẹ́gẹ́ bí akẹ́kọ̀ó ọlọ́dún kejì ní Grayson College, Priscilla ṣe ìfarahàn ní ẹ̀ẹ̀mẹfà, tó sì gba pọ́íǹtì 8.5 points àti àtúnṣe 8.0 lórí ayò kọ̀ọ̀kan, nínú ìdíje pẹ̀lú Oklahoma Wesleyan.

Ní ọdún 2023, ó tẹwọ́bọ̀wé pẹ̀lú UTEP, níbi tí ó ti darapọ̀ mọ́ẹgbẹ́ náà fún ìdíje ti ọdún 2024–25.[4]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Abey Priscilla joins Jane Asinde at UTEP women’s basketball team". NBS Sport. 2023-11-17. Retrieved 2024-03-21. 
  2. "Priscilla Abey". FIBA 3x3. Retrieved 2024-03-21. 
  3. "Priscilla Abey". FIBA.basketball. 1999-12-22. Retrieved 2024-03-21. 
  4. Kaweru, Franklin (2023-11-17). "Priscilla Abey set to join UTEP next year". Kawowo Sports. Retrieved 2024-03-21.