Priscilla Mensah
Priscilla Mensah jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 19, óṣu April ni ọdun 1974. Agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin portal gẹgẹbi goalkeeper.
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 19 Oṣù Kẹrin 1974 | ||
Playing position | Goalkeeper | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Postal Ladies | |||
National team‡ | |||
Ghana women's national football team | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Aṣeyọri
àtúnṣe- Priscilla kopa ninu FIFA Cup awọn obinrin agbaye ti ọdun 1999.