Pròkáríọ́tì
(Àtúnjúwe láti Prokaryote)
Pròkáríọ́tì (pípè /proʊˈkæri.oʊts/ tàbí /proʊˈkæriəts/) ni àdìpọ̀ àwọn ohun ẹlẹ́ẹ̀mí tí wọn kò ní kóróonú àhámọ́ (= karyon), tàbí àwọn apáinú tí mẹ́mbránì yí ká míràn. Àwọn ohun ẹlẹ́ẹ̀mí tí àhámọ́ wọ́n ní kóróonú ni à únpè ní eukaryotes. Ọ̀pọ̀ àwọn Most pròkáríọ́tì jẹ́ oníàhámọ́kan, sùgbọ́n àwọn díẹ̀ bí i àwọn miksobaktéríà ní ìpele oníàhámọ́púpọ̀ nínú ìṣe ayé wọn.[1]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Kaiser D (October 2003). "Coupling cell movement to multicellular development in myxobacteria". Nat. Rev. Microbiol. 1 (1): 45–54. doi:10.1038/nrmicro733. PMID 15040179.