Promise Amukamara (born 22 June 1993) is a Nigerian-American basketball player for Charnay Basket Bourgogne SUD (FRA) and the Nigerian national team.[1]

Promise Amukamara
No. 10 – Charnay BB
PositionPoint guard
LeagueLFB
Personal information
Born22 Oṣù Kẹfà 1993 (1993-06-22) (ọmọ ọdún 31)
New Jersey, United States
NationalityAmerican / Nigerian
Listed height1.75 m (5 ft 9 in)
Career information
High schoolApollo (Glendale, Arizona)
CollegeArizona State (2011–2015)
NBA draft2015 / Round: 3 / Pick: 36k overall
Selected by the Phoenix Mercury

Promise Amukamara tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún osù kẹfà ọdún 1993 jẹ́ agbá bọ́ọ̀lù inú agbọ̀n ti orílẹ̀-ède Nàìjíríà-Amẹrika fún Charnay Basket Bourgogne SUD (FRA) àti ẹgbẹ́ orílẹ̀-ède Nàìjíríà .

Ìbẹ̀rẹ̀ Ìgbésí ayé àti ẹ̀kọ́

àtúnṣe

Promise ga ní ẹsẹ̀ bàtà marun ó lé inch mẹsan(175 cm).[2] Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè láti ilé-ìwé gíga ti Arizona University [3]. Ó tún jẹ́ àbúrò fún Super Bowl XLVI Champion, New York Giants tẹ́lẹ̀ rí cornerback Prince Amukamara .

Iṣẹ́ tí ó yàn

àtúnṣe

Promise jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ D'Tigress, ẹgbẹ́ agbá bọ́ọ̀lù inú agbọ̀n obìnrin ti orílẹ̀-ède Nàìjíríà. Ó jẹ́ olùsọ́ ààyè ti ẹgbẹ́ tí ó ṣeré níbi 2020 Olympic Gamesní Tokyo.[4][5] Ó tún kópa níbi FIBA Women's Basketball World Cup ti ọdún 2018.[6]

Àwọn àṣeyọrí rẹ̀

àtúnṣe
  • O jú àmì mẹwa fún eré kọ̀ọ̀kan ní Tokyo, ní ọdún 2020
  • Akẹkọọ̀ jade akọ̀kọ̀ ní ilé ìwé gíga Arizona State University tí ó jẹ́ agbá bọ́ọ̀lù inú agbọ̀n obìnrin tí ó kájú láti ṣe ẹgbẹ́ Olympic
  • Ọmọ ẹgbẹ́ 2019 FIBA African Championship Gold Medal tí ó kópa nínu Ìdíje ayẹyẹ Pre-Olympic [7]
  • agbá bọ́ọ̀lù inú agbọ̀n Arizona ti ọdún 2011 [7]
  • Ẹni tí ó yára jùlọ nínú ọgọrún mita àti igba mita gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó sẹ̀sẹ̀ wọ ilé-ìwé gíga [7]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Eurobasket. "Promise Amukamara Player Profile, Charnay Basket Bourgogne SUD, News, Stats - Eurobasket". Eurobasket LLC. Retrieved 2021-05-29. 
  2. "Promise Amukamara - Player Profile". FIBA.basketball (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-17. 
  3. Hillman, Jenna; of 2021, ASU Class. "Dribbling to Tokyo: Promise Amukamara Ready to Compete for Nigeria". Arizona State University Athletics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-17. 
  4. "D'Tigress players lament marginalization, hijack of donations made to team". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-10-13. Retrieved 2022-05-17. 
  5. "D'Tigress will make Nigerians proud at Tokyo 2020 — Amukamara". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-04-18. Retrieved 2022-05-17. 
  6. "Sarah OGOKE at the FIBA Women's Basketball World Cup 2018". FIBA.basketball (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-05-29. 
  7. 7.0 7.1 7.2 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :0