Proturan
(Àtúnjúwe láti Protura)
Protura, tàbí àwọn proturan, tí ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ conehead,[1][2] jẹ́ àwọ́n ẹrankó kékèké (<2 mm ní gígún), tí wọ́n ń gbé inú iyẹ̀pẹ̀, wọ́n kéré tó bẹ́ẹ̀ tí a kò ṣàkíyèsí títí di ogún ọ̀rundún sẹ́yìn. Protura jẹ́ ẹgbẹ́ àwọn hexapod tí a kà sí àwon kòkòrò insects, ti a má ań kó wọn sí àyè wọn lọ́tọ̀.[3].
Protura | |
---|---|
Ìṣètò onísáyẹ́nsì | |
Ìjọba: | |
Ará: | |
Subphylum: | |
Ẹgbẹ́: | |
Ìtò: | Protura Silvestri, 1907
|
Families | |
Àwọn ìtọ̣́kasí
àtúnṣe- ↑ "Proturans / Coneheads".
- ↑ "Order Protura - Coneheads". http://bugguide.net bugguide.net, hosted by Iowa State University Department of Entomology.
- ↑ Charles S. Henry (2005)