Queen Nwokoye
Queen Nwokoye (tí a bí ní 11 Oṣù Kẹẹ̀jọ, Ọdún 1982) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[2][3] Ó gbajúmọ̀ fún kíkó ipa olú-ẹ̀dá-ìtàn nínu eré kan ti ọdún 2014 tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Chetanna, èyítí ó ṣokùn fa tí wọ́n fi yàán fún àmì-ẹ̀yẹ "Òṣèrébìnrin tó dára jùlọ" níbi ayẹyẹ Africa Movie Academy Awards .[4]
Queen Nwokoye | |
---|---|
Nwokoye in 2016 | |
Ọjọ́ìbí | 11 Oṣù Kẹjọ 1982[1] Lagos State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Nnamdi Azikiwe University |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2004 – present |
Website | queennwokoye.com.ng |
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeÌpínlẹ̀ Èkó ni wọ́n bí Nwokoye sí, ṣùgbọ́n àwọn òbí rẹ̀ wá láti Ìpínlẹ̀ Anámbra.[5] Ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Air Force Primary School. Ó sì tún parí ẹ̀kọ́ girama rẹ̀ ní Queen's College ti ìlú Enúgu ṣááju kí ó tó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì Nnamdi Azikiwe ní ìlú Awka, Ìpínlẹ̀ Anámbra níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀ àwùjọ. Ó dàgbà pẹ̀lú ìpinnu láti di amòfin.[6]
Iṣẹ́ ìṣe rẹ̀
àtúnṣeLáti ìgbà tí ó ti ṣe àkọ́kọ́ eré rẹ̀ ní ọdún 2004, Nwokoye ti ṣe bẹ́ẹ̀ kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù ti Nàìjíríà, tó sì tún gba aẁọn àmì-ẹ̀yẹ lóríṣiríṣi[7][8]
Àtòjọ àwọn àṣàyàn eré rẹ̀
àtúnṣe- Nna Men (2004)
- His Majesty (2004)
- The Girl is Mine (2004)
- Security Risk (2004)
- Save The Baby (2005)
- Back Drop (2005)
- Speak The Word (2006)
- My Girlfriend (2006)
- Last Kobo (2006)
- Lady of Faith (2006)
- Disco Dance (2006)
- Clash of Interest (2006)
- The Last Supper (2007)
- When You Are Mine (2007)
- The Cabals (2007)
- Show Me Heaven (2007)
- Short of Time (2007)
- Sand in My Shoes (2007)
- Powerful Civilian (2007)
- Old Cargos (2007)
- My Everlasting Love (2007)
- Confidential Romance (2007)
- The Evil Queen (2008)
- Temple of Justice (2008)
- Onoja (2008)
- Heart of a Slave (2008)
- Female Lion (2008)
- Angelic Bride (2008)
- Prince of The Niger (2009)
- Personal Desire (2009)
- League of Gentlemen (2009)
- Last Mogul of the League (2009)
- Jealous Friend (2009)
- Makers of Justice (2010)
- Mirror of Life (2011)
- End of Mirror of Life (2011)
- Chetanna (2014)
- Nkwocha (2012)
- Ekwonga (2013)
- Ada Mbano (2014)
- Agaracha (2016)[9]
- New Educated Housewife (2017)
- Blind Bartimus (2015)
- Coffin Buburu (2016
- Iyawo Ti a Yan
Àwọn ìyẹ̀sí rẹ̀
àtúnṣeỌdún | Ayẹyẹ | Ẹ̀ka | Èsì | Ìtọ́kasí |
---|---|---|---|---|
2011 | 2011 Best of Nollywood Awards | Best Supporting Actress in an English Movie | Wọ́n Yàán | [10] |
Fresh Scandal Free Actress | Gbàá | [11] | ||
2012 | 2012 Nollywood Movies Awards | Best Actress in an Indigenous Movie (non-English speaking language) | Wọ́n Yàán | |
2013 | 2013 Best of Nollywood Awards | Best Lead Actress in an English Movie | Wọ́n Yàán | |
2014 | 2014 Nollywood Movies Awards | Best Indigenous Actress | Wọ́n Yàán | |
2015 | 11th Africa Movie Academy Awards | Best Actress in a Leading Role | Wọ́n Yàán | |
2015 Zulu African Film Academy Awards | Best Actor Indigenous (Female) | Gbàá | [12] | |
2015 Best of Nollywood Awards | Best Actress in a Leading Role (Igbo) | Gbàá | [13] | |
2016 | 2016 City People Entertainment Awards | Face of Nollywood Award (English) | Gbàá | [14] |
Ọ̀rọ̀ ayẹ́ rẹ̀
àtúnṣeNwokoye ti ṣe ìgbeyàwó pẹ̀lú Ọ̀gbẹ́ni Uzoma, ó sì ti bí àwọn ọmọ ìbejì okùnrin[15] àti ọmọbìnrin kan. [16]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "ABOUT - Queen Nwokoye". Archived from the original on 2019-08-26. Retrieved 2016-05-22. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Nollywood: Queen Nwokoye, Rachel Okonkwo allegedly fight over movie role". Daily Post Nigeria. Retrieved 22 May 2016.
- ↑ "In Session With The Talented Queen Nwokoye, Ada Mbano Of Nollywood". guardian.ng. Retrieved 22 May 2016.
- ↑ "Will Ini Edo win 2015 AMAA Best Actress award tonight?". Vanguard News. 26 September 2015. Retrieved 22 May 2016.
- ↑ H. Igwe (6 October 2015). "I Actually Wanted To Be A Lawyer But It Did Not Work Out – Actress Queen Nwokoye". Naij.com - Nigeria news. Retrieved 22 May 2016.
- ↑ H. Igwe (6 October 2015). "I Actually Wanted To Be A Lawyer But It Did Not Work Out – Actress Queen Nwokoye". Naij.com - Nigeria news. Retrieved 22 May 2016.
- ↑ Chidumga Izuzu (11 August 2015). "Queen Nwokoye: 5 things you probably don't know about actress". pulse.ng. Archived from the original on 20 May 2016. Retrieved 22 May 2016.
- ↑ "AMAA Best Actress: Queen Nwokoye Hopeful To Beat Ini Edo And Jocelyn Dumas". Entertainment Express. Retrieved 22 May 2016.
- ↑ Latest 2016 Nollywood movie, IrokoTV, retrieved 15 October 2016
- ↑ "The 2011 Best Of Nollywood (BON) Awards hosted by Ini Edo & Tee-A – Nominees List & “Best Kiss” Special Award". BellaNaija. Retrieved 22 May 2016.
- ↑ Osaremen Ehi James/Nigeriafilms.com. "Queen Nwokoye Becomes Busiest Nollywood Actress". nigeriafilms.com. Archived from the original on 4 June 2016. Retrieved 22 May 2016. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Chidumga Izuzu (3 November 2015). "Queen Nwokoye: Actress wins 'Best Actor Indigenous Female' at ZAFAA 2015". pulse.ng. Archived from the original on 24 June 2016. Retrieved 22 May 2016.
- ↑ Fu'ad Lawal (14 December 2015). "Best of Nollywood Awards 2015: See full list of winners". pulse.ng. Archived from the original on 7 August 2017. Retrieved 22 May 2016.
- ↑ Adedayo Showemimo (26 July 2016). "Full List Of Winners at 2016 City People Entertainment Awards". Nigerian Entertainment Today. Archived from the original on 8 December 2016. https://web.archive.org/web/20161208102412/http://thenet.ng/2016/07/full-list-of-winners-at-2016-city-people-entertainment-awards/. Retrieved 27 July 2016.
- ↑ "Actress Queen Nwokoye Shares Picture Of Her Twin Sons". INFORMATION NIGERIA. Retrieved 22 May 2016.
- ↑ "Actress Queen Nwokoye Shares Picture Of Her Twin Sons". INFORMATION NIGERIA. Retrieved 22 May 2016.