Ronke Ojo tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù keje ọdún 1974 (July 17, 1974)tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Rónkẹ́ Òṣòdì-Òkè jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ Yorùbá láti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1]Bákan náà, Rónkẹ́ jẹ́ akọrin

Ronke Ojo
Ronke Ojo
Ọjọ́ìbí17 Oṣù Keje 1974 (1974-07-17) (ọmọ ọdún 50)
Oworoshonki, Kosofe, Lagos State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iṣẹ́
  • actress
  • producer
  • director
Ìgbà iṣẹ́1998–present
Olólùfẹ́
Anthony Gbolahan (m. 2009)

Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́

àtúnṣe

Rónkẹ́ jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Oǹdó, ṣùgbọ́n ìpínlẹ̀ Èkó, ní ìlú Òwòròǹṣòkí ni ó ti ṣe kékeré dàgbà.[2][3] [4] Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà pẹ̀lú ẹgbẹ́ òṣèré tíátà kan tí wọ́n ń pè Star ParadeFádèyí Olóró jẹ́ olùdásílẹ̀ rẹ̀. Ìràwọ̀ Rónkẹ́ kò tètè tàn àfi lọ́dún 2000 tí ó gbé sinimá àgbéléwò kan jáde tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Òṣòdì-Òké.[5][6] Lọ́dún 2014, ó kán ságbo orin.[7][8] In 2015, she released a single titled Ori Mi which featured 9ice.[9]

Àtòjọ díẹ̀ nínú àwọn sinimá-àgbéléwò rẹ̀

àtúnṣe
  • Succubus (2014)
  • Asán Layé
  • Eèsù
  • Agbèrè Ojú
  • Return of Jenifa
  • Abeke Aleko
  • Abeke Eleko 2
  • Ajílodà
  • Àìmàsìkò Ẹ̀dá (2006)
  • Okùn Ìfẹ́ 2 (2004)
  • Okùn Ìfẹ́ (2004)
  • Àṣírí (2002)
  • Òṣòdì Òkè (2000)

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Top Nollywood Actress, Ronke Oshodi-Oke in a recent interview with Vanguard revealed that her big boobs brought her into limelight". Naij. Archived from the original on December 10, 2015. Retrieved December 12, 2014. 
  2. "Ronke Ojo". iroktv.com. Archived from the original on 2019-12-25. Retrieved 2019-12-25. 
  3. Adams Odunayo (8 October 2014). "Actress Ronke Oshodi Reveals Her Greatest Regret". Naij.com - Nigeria news. Retrieved 5 December 2015. 
  4. "YORUBA ACTRESS,RONKE OSHODI OKE WEDS SYLVESTER OMOGBOLAHAN IN NIGERIA". Nigeria Films. February 3, 2009. http://www.modernghana.com/movie/3885/3/yoruba-actressronke-oshodi-oke-weds-sylvester-omog.html. 
  5. "My boobs brought me to limelight—— Ronke Ojo". Vanguard News. 26 October 2014. Retrieved 5 December 2015. 
  6. Ayo Onikoyi. "My boobs brought me to limelight—— Ronke Ojo". Vanguard Nigeria. http://www.vanguardngr.com/2014/10/my-boobs-brought-me-to-limelight-ronke-ojo/. Retrieved October 26, 2014. 
  7. Esho Wemimo (24 November 2014). "Ronke Oshodi-Oke: Actress drops new album". pulse.ng. Archived from the original on 8 December 2015. Retrieved 5 December 2015. 
  8. ""Why I won't release my album yet" – Ronke Oshodi-Oke". Pulse NG. April 7, 2015. Archived from the original on March 4, 2016. Retrieved December 25, 2019. 
  9. Jimmy King (April 7, 2015). "Ronke Oshodi Oke – "Ori Mi" ft. 9ice (Prod. by ID Cabasa)". tooXclusive. http://tooxclusive.com/downloadmp3/ronke-oshodi-oke-ori-mi-ft-9ice-prod-by-id-cabasa//.