Rẹ̀mí Abíọ́lá
Rẹ̀mí Abíọlá tí wọ́n bí ní oṣù Kẹwàá ọdún 1953 tí ó jáde láyé ní oṣù keje ọdún 2009. Jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olùgbéré-jáde, ati adarí eré sinimá ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ìyàwó Moshood Abíọlá.[1] Rẹ̀mí papò dà ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 2009, látàrí àìsàn jẹjẹrẹ tí jákùn ẹ̀mí rẹ̀. Àwọn ọmọ méjì ni ó gbẹ̀yìn olóògbé náà. [2][3][4]
Rẹ̀mí Abíólá | |
---|---|
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ |
|
Olólùfẹ́ | Moshood Abiola |
Àwọn ọmọ | 2 |
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeRẹ̀mí kẹ́kọ̀ọ́ nípa eré-oníṣe ní fielding school for dramatic Arts ní ìlú England ní àsìkò ọdún 1970s, lẹ́yìn tí ó fisẹ́ sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ònbánisọ̀rọ̀ ní ilé-iṣẹ́ Nigeria Airways. Nígbà tí ó padà sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó kóp nínú àwọn eré orí ẹrọ amóhù-máwòrán lóríṣirí lábẹ́ àwọn ògbóntagì eléré bíi: Báyọ̀ Àwàlà àti Olóyè Túndé Olóyédé.[5] [6]
3 tún lè wo
àtúnṣeÀwọn Ìtókasí
àtúnṣe- ↑ "Sunset for top yoruba actress-Remi Abiola". Vanguard News. Retrieved 21 April 2015.
- ↑ "How Star actress Remi Abiola died". World News. April 8, 2009. http://article.wn.com/view/2009/08/04/How_Star_actress_Remi_Abiola_died/. Retrieved April 22, 2015.
- ↑ "nollywood actress-Remi Abiola dies". Vanguard News. Retrieved 21 April 2015.
- ↑ Opeyemi Gbenga Mustapha (June 14, 2014). "Curbing the cancer menace". The Nation. http://thenationonlineng.net/new/curbing-cancer-menace/. Retrieved April 22, 2015.
- ↑ https://www.vanguardngr.com/2009/07/sunset-for-top-yoruba-actress-remi-abiola/
- ↑ https://www.thenigerianvoice.com/movie/3326/i-was-mkos-wife-not-mistress-remi-abiola.html