Ribonúkléù kíkan
(Àtúnjúwe láti RNA)
Ribonúkléù kíkan tabi ásìdì ribonúkléù (ribonucleic acid) (Pípè: /raɪbɵ.njuːˌkleɪ.ɨk ˈæsɪd/), tabi RNA, je ikan ninu awon horogigun agba meta (lapapo mo DNA ati awon proteini) ti won se koko fun gbogbo iru awon ohun alaye.
Bi DNA, RNA na je dida pelu ewon gigun to unje nukleotidi. Nukleotidi kookan ni ipilenukleu (pipe nigba mi ni ipile oloponitrojin), suga ribosi kan, ati adipo oniyofosforu kan.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |