Àdàkọ:Use Nigerian English Àdàkọ:More citations needed

Rabilu Musa
Ọjọ́ìbí(1971-12-12)12 Oṣù Kejìlá 1971
Danlasan, Kano, Nigeria
Aláìsí9 December 2014(2014-12-09) (ọmọ ọdún 42)
Kano, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Ẹ̀kọ́Grade II
Iléẹ̀kọ́ gígaGovernment Teachers College Wudil, Kano, Nigeria
Iṣẹ́Òṣèré, Olùgbéré-jáde, ati adarí eré
Ìgbà iṣẹ́1997–2014
Olólùfẹ́3
Àwọn ọmọ7
AwardsSee below

Rabilu Musa, tí gbogbonènìyàn mọ̀ sí Dan Ibro tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kejìlá ọdún 1971, jẹ́ ògbóntagì òṣèré, aláwàdà, olùgbéré-jáde, àti adarí eré Hausa, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà . Òun ni wọ́n ń pè ní asíwájú ati olùdásílẹ̀ agbo Kannywood , òin náà tún ni ó tún mọ awàdà ṣe jùlọ nínú gbogbo awọn òṣèré aláwàdà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣáájú kí ó papò dà ní ọdún 2014.[1]

Ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Dan Ibro lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákòọ́bẹ̀rẹ̀ ti "Danlasan" tí ó wà ní Warawa, ó sì lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama "Government Teachers College" tí ó wà ní ìlú Wudil ní Ìpínlẹ̀ Kánò. Ó dara pọ̀ mọ́ ilé-iṣẹ́ àtúnṣe awọn ẹlẹ́wọ̀n ní ọdún 1991, tí ó sì fisẹ́ náà sílẹ̀ ní lẹ́yìn ọdún díẹ̀, láti dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèré tíátà. Eré rẹ̀ akọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ gbé jáde ni 'Yar Mai Ganye which promoted his career.[citation needed]

Popular songs include Bayanin Naira, Idi Wanzami, Dureba Makaho.[citation needed]

Early career

àtúnṣe

Rabilu Musa became popular in Hausa movie cinema few years after when he joined the industry. Some of his popular movies includes Andamali, Ibro Aloko, Ibro Angon Hajiya, Ibro Dan Fulani. His career as an actor continues when he turned to be a full-time comedian and began singing with his popular songs such as Bayanin Naira, Idi Wanzami, Direba Makaho.[2]

Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀

àtúnṣe
↓ Eré Ọdún
'Yar Mai Ganye ND
A Cuci Maza 2013
Akasa Atsare 2011
Allo ND
Andamali 2013
Bita Zai Zai ND
Borin Ibro ND
Dan Auta Amalala ND
Dan Gatan Ibro ND
Dawa Dai ND
Gabar Ibro ND
Ibro Alkali 2012
Ibro Aloko 2007
Ibro Angon Hajiya ND
Ibro Ba Sulhu 2014
Ibro Dan Almajiri ND
Ibro Dan Chacha ND
Ibro Dan Daudu 2011
Ibro Dan Fulani ND
Ibro Dan Nageriya ND
Ibro Dan Polio ND
Ibro Dan Siyasa ND
Ibro Dan Zaki ND
Ibro Dawo-Dawo 2011
Ibro Mahaukaci ND
Ibro Mai Babbar Riga ND
Ibro Police ND
Ibro Producer 2011
Ibro Saye da Sayarwa ND
Ibro Sudan ND
Ibro Wuju Wuju Basu 2011
Ibro Ya Auri Baturiya 2010
Kankamba ND
Karfen Nasara 2015
Kaso ND
Kowa Yabi ND
Mahauta da Fulani ND
Mai Dalilin Aure (Match Maker) 2014
Maidaben Bagi ND
Mazan Baci ND
Namamajo ND
Ragon Shiri ND
So Kasheni ND
Sukuni ND
Tun Ran Gini ND
Uwar Gulma (The Mother of Gossip) 2015
Year Award Category Film Result
2014 2014 Nigeria Entertainment Awards Best Supporting Actor Special Recognition Yàán
2015 2nd Kannywood/MTN Awards Best Comedian (Jurors Choice Awards) Posthumous Award[3] Gbàá

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Comedian ‘Dan Ibro’ buried in Kano". Premium Times Nigeria. 2014-12-10. Retrieved 2020-11-18. 
  2. "Best of Rabilu Musa Dan Ibro for Android - APK Download". APKPure.com. 2018-05-25. Retrieved 2020-11-18. 
  3. Lere, Mohammed (1 February 2015). "Late Ibro honoured at MTN Kannywood Awards 2015". Nigeria: Premium Times. Retrieved 18 May 2020. 

Àdàkọ:Authority control


Àdàkọ:Nigeria-actor-stub