Rachael Yamala jẹ agbàbọọlu lobinrin orilẹ ede Naigiria ti a bini 12, óṣu Febuary ni ọdun 1975. Arabinrin naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun team awọn obinrin naigiria ti national lori bọọlu[1].

Rachael Yamala
Personal information
Ọjọ́ ìbí12 Oṣù Kejì 1975 (1975-02-12) (ọmọ ọdún 49)
Playing positionMidfielder
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Kakanfo Babes
National team
Nigeria women's national football team
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 16 November 1991 (before the 1991 FIFA Women's World Cup)

Àṣèyọri

àtúnṣe
  • Arabinrin naa wa lara ọkan ninu team Cup FIFA awọn obinrin àgbaye ni ọdun 1991[2].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://ng.soccerway.com/players/rachael-yamala/291481/
  2. https://alchetron.com/Rachael-Yamala