Racheal Onígà
Racheal Onígà (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ ketalelogun oṣù karùn-ún ọdún 1957) jẹ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin ọmọ bíbí ìlú Eku ní ìpínlẹ̀ Delta lorílẹ̀ èdè Nàìjíríà . Bí ó ṣe gbajúmọ̀ nínú eré sinimá àgbéléwò èdè Yorùbá, bẹ́ẹ̀ náà ló dáńtọ́ nínú sinimá àgbéléwò èdè Gẹ̀ẹ́sì.[1] [2]
Rachael Oniga | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 23 Oṣù Kàrún 1957 Delta State , Nigeria. |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Orúkọ míràn | Tabuno |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | film actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1993-present |
Notable work | Sango (Film) |
Àtòjọ díẹ̀ nínú àwọn sinimá-àgbéléwò rẹ̀
àtúnṣe- ṣàǹgó (1997)
- Out of Bounds (1997)
- Ówò Blow (1997)
- Passion of Mind (2004)
- Power Of Sin,
- Restless Mind
- Doctor Bello (2013)
- 30 Days in Atlanta (2014)
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Nollywood/ Nigeria No.1 movies/ films resources online". Nollywood/ Nigeria No.1 movies/ films resources online. 2019-10-21. Retrieved 2019-12-16.
- ↑ "Films". Africultures. Retrieved 2019-12-16.