Rafael Francisco Alburquerque De Castro (ojoibi 14 June 1940, ni Santo Domingo) ni Igbakeji Aare orile-ede Dominiki Olominira, labe Aare Leonel Fernández, lati August 2004 to si je titundiboyan ni May 2008. O bura si ise ni 16 August 2008.[1]

Àwòrán Rafael Albuquerque àti Jacques Wagner.
Rafael Alburquerque
Vice President of the Dominican Republic
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
16 August 2004
ÀàrẹLeonel Fernández
AsíwájúMilagros Ortiz Bosch
Arọ́pòIncumbent
Secretary of Labor
In office
16 August 1996 – 16 August 2000
ÀàrẹLeonel Fernández
AsíwájúDr. Juan Arístides Taveras Guzmán
Arọ́pòMilton Ray Guevara
Secretary of Labor
In office
04 March 1991 – 05 May 1996
ÀàrẹJoaquín Balaguer
AsíwájúDr. Washington De Peña
Arọ́pòDr. Juan Arístides Taveras Guzmán
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí14 Oṣù Kẹfà 1940 (1940-06-14) (ọmọ ọdún 84)
Santo Domingo, Dominican Republic
Ẹgbẹ́ olóṣèlúDominican Liberation Party
(Àwọn) olólùfẹ́Martha Montes de Oca
Alma materUniversidad Autónoma de Santo Domingo