Rasad
Rasad (fl. 1078), tí wọ́n tún máa ń pè ní Sayyida Rasad, fìgbà kan jẹ́ obìnrin olóṣèlú ti ilẹ̀ Egyptian Caliph mother. Òun ni adelé Fatimid Egypt gẹ́gẹ́ bí i obìnrin olókìkí, tó tún jẹ́ ìyá ọmọ rẹ̀, Fatimid caliph al-Mustansir Billah, láàárín ọdún 1044 wọ 1071.[1][2] Orúkọ yìí, Rasad túmọ̀ sí "ìwòye".[3]
Rasad | |
---|---|
Reign | 1044 – 1071 |
Spouse | Al-Zahir li-i'zaz Din Allah |
Issue | |
Al-Mustansir Billah | |
Full name | |
Malika Rasad Umm Ma'ad | |
Born | Unknown date |
Died | after 1078 Cairo, Egypt |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Cortese & Calderini 2006.
- ↑ Candido, Mariana P. (2020-03-31), "Women and Slavery in Africa", Oxford Research Encyclopedia of African History (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), ISBN 978-0-19-027773-4, doi:10.1093/acrefore/9780190277734.013.466, retrieved 2023-07-18
- ↑ El-Azhari, Taef (2021). Queens, Eunuchs, and Concubines in Islamic History, 661-1257. Edinburgh University Press. pp. 196–252. ISBN 9781474423199. https://edinburghuniversitypress.com/pub/media/resources/9781474423199_4._Fatimid_Royal_Women_and_Royal_Concubines_in_Politics.pdf. Retrieved 22 March 2022.