Rashid Bakr (Olóṣèlú)
El Rashid El Tahir Bakr (ọjọ́ kẹrinlélógún oṣù kẹfà ọdún 1933[1] – oṣù kọkànlá oṣù mẹta ọdún 1988),[2] ẹni tí a bí ní Karkoj Blue Nile ní Sudan. Ní ọdún 1958, ó kàwé gboyè ní eka ìmọ̀ òfin ti Yunifásítì Khartoum.[3] Òun ni Ìgbà kejì ààrẹ Sudan àti Mínísítà àgbà Sudan láti ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹjọ 1976 títí di ọjọ́ Kẹ̀wá oṣù kẹsàn-án ọdún 1977. Ó jẹ́ alága ilé ìgbìmọ̀ asofin láti ọdún 1974 di 1977 àti láti 1980 di 1981.[4] He was Foreign Minister of Sudan from 1977 to 1980.
Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Sudan Socialist Union.[5]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Kramer, Robert S.; Lobban, Richard Andrew; Fluehr-Lobban, Carolyn (2013). Historical Dictionary of the Sudan. ISBN 9780810861800. https://books.google.com/books?id=WAs7lGNkVBkC&q=El+Rashid+El+Tahir+Bakr&pg=PA364.
- ↑ Biography of Rashid Bakr Archived 2017-09-09 at the Wayback Machine. Àdàkọ:In lang
- ↑ Staff Prime Ministers of Sudan Archived 2016-10-17 at the Wayback Machine. Sudanese Embassy, Retrieved 22 August 2012
- ↑ "Archived copy". Archived from the original on 2019-05-04. Retrieved 2019-03-01. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "The Sudan" Archived 2015-11-20 at the Wayback Machine., worldstatesman.org (accessed 28 October 2010)