Razaq Olayiwola tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Òjòpagogo jẹ́ Gbajúmọ̀ òṣèré ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. [1] Òun ni ọkọ gbajúgbajà òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò, Mojí Afọláyan.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe