Rebecca Kalu jẹ Agbààbọlu lobinrin orilẹ ede Naigiria ti a bini 12, óṣu June ni ọdun 1990. Arabinrin naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun team national U-20 lori bọọlu ni ọdun 2008[1].

Rebecca Kalu
Personal information
Ọjọ́ ìbí12 Oṣù Kẹfà 1990 (1990-06-12) (ọmọ ọdún 34)
Playing positionMidfielder
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2009Piteå IF
National team
Nigeria women's national football team
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 26 June 2011 (before the 2011 FIFA Women's World Cup)

Aṣeyọri

àtúnṣe
  • Rebecca kopa ninu Cup FIFA U-20 awọn obinrin àgbàye[2].
  • Arabinrin naa ṣere fun Piteà IF fun club level to waye ni sweden ni ọdun 2009[3].
  • Arabinrin naa tun ṣe àṣoju fun orilẹ ede naogiria fun Cup FIFA awọn obinrin àgbàye ni ọdun 2011[4].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://ng.soccerway.com/players/rebecca-kalu/98082/
  2. https://www.kickoff.com/news/articles/local/categories/news/falconets-depart-for-fifa-u-20-womens-world-cup/525908[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. https://profilesinfo.com/rebecca-kalu-wiki-networth-age/[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  4. https://www.fifa.com/tournaments/womens/womensworldcup/germany2011/teams/1882893