Regina Ansah
Regina Ansah jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 23, óṣu August ni ọdun 1974. Agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin Bluna gẹgẹbi defender[1].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 23 Oṣù Kẹjọ 1974 | ||
Playing position | Defender | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Bluna Ladies | |||
National team‡ | |||
Ghana women's national football team | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àṣeyọri
àtúnṣe- Regina kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ti 1999[2].