Remi Abiola
òṣèré orí ìtàgé
Rẹ̀mí Abíólá (Oṣù Kẹẹ̀jọ Ọdún 1953 - Oṣù Keèje Ọdún 2009) jẹ́ òṣèré fiimu ti Ìlu Nàìjíríà àti ìyàwó olóògbé Moshood Abíola, ẹni tí ó ṣe pàtàkì nínú olùṣòwò àti olósèlú ìlú Nàìjíríà.[1] Rèmi? kú sí Ìlu New York ní ọjọ́ mókàndínlógbòn, Oṣù Keèje, ọdún 2009 lẹ́hìn tí ó pàdánù ogun pẹ̀lú aìsàn cancer. Ó fi àwọn ọmọ méjì sáyé lo tí orúko won sì n jẹ́ Abímbọ́lá Umardeen ati Ọlájùmòké Adétòun.[2][3][4]
Remi Abiola | |
---|---|
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ |
|
Olólùfẹ́ | Moshood Abiola |
Àwọn ọmọ | 2 |
Iṣẹ́ ìṣe
àtúnṣeRẹ̀mí kọ́ṣẹ́ òṣèré ní ilé-ìwé tó n bẹ fún eré orí-ìtàgé ní Ìlu England ní àwọn ọdún 70 lẹ́hìn tí ó kúrò ní ìdi isẹ́ Nigerian Airways gẹ́gẹ́ bi olùtọ́jú èro baalu. Nígbàtí ó padà wá sí Nàìjíríà, ó ṣe àfẹ́rí àwọn ipa ó sì tún kópa nínú eré Telifíṣọ́nù tí Báyò Àwálá àti Olóyè Túndé Olóyède ṣe, èyítí wọ́n gbé jáde lóri NTA Channel 10.[5][6]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Sunset for top yoruba actress-Remi Abiola". Vanguard News. Retrieved 21 April 2015.
- ↑ "How Star actress Remi Abiola died". World News. April 8, 2009. http://article.wn.com/view/2009/08/04/How_Star_actress_Remi_Abiola_died/. Retrieved April 22, 2015.
- ↑ "nollywood actress-Remi Abiola dies". Vanguard News. Retrieved 21 April 2015.
- ↑ Opeyemi Gbenga Mustapha (June 14, 2014). "Curbing the cancer menace". The Nation. http://thenationonlineng.net/new/curbing-cancer-menace/. Retrieved April 22, 2015.
- ↑ https://www.vanguardngr.com/2009/07/sunset-for-top-yoruba-actress-remi-abiola/
- ↑ https://www.thenigerianvoice.com/movie/3326/i-was-mkos-wife-not-mistress-remi-abiola.html