Rẹ̀mí Àdùkẹ́ Adédèjì tí a bí ní ọdún 1937 jẹ́ Oǹkọ̀wé ọ̀jẹ̀-wẹ́wẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1][2][3]

Rẹ̀mí Àdùkẹ́ Adédèjì
Ọjọ́ìbí1937
Okemesi
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iṣẹ́Children's writer

Ìgbésí ayé

àtúnṣe

Adedeji jẹ ọmọ bíbí ìlú Okemesi ni Ekiti State ni ọdún 1937.[4] ojú gba Adedeji tí nítorí àwọn ìwé tí ọ ko ni nipasẹ iwa ati ìṣe ile wa . Púpò ni iwe ni o kò nipa ìtàn àwọn ọmọ Naijiria . O ṣe atejade The fat woman ni ọdún 1973. A Yàn gẹgẹ bí oluranlọwọ a tun ìwé tó academic journal, Bookbird. Ìwé rẹ sọrọ nipa ìjàpá. Ìwé ọdún 1986 "Moonlight Stories" sọrọ nipa Just-so stories ìdí tí ẹkùn fi pa lórí ati ìdí tí ikarahun ìjàpá fi sàn. [5]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "African Books Collective: Remi Adedeji". African Books Collective. Retrieved 2019-12-26. 
  2. "Remi Adedeji Books - Biography and List of Works - Author of 'Moonlight Stories'". Biblio.com. Retrieved 2019-12-26. 
  3. Revolvy, LLC (2010-01-01). ""Remi Adedeji" on Revolvy.com". Revolvy. Retrieved 2019-12-26. 
  4. Remi Adedeji, Ohio University, Retrieved 27 February 2016
  5. Moonlight Stories, African Book Collective, Retrieved 27 February 2016