Reuben Fasoranti
Reuben Fáṣànràntì jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́tàléláàádọ́rùún (93) láti Ìpínlẹ̀ Òndó lápá Gúsù Ìwọ̀-Oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà [1] Ó ti fìgbà kan jẹ́ olórí abala kan nínú ẹgbẹ́ Afẹ́nifẹ́re, ẹgbẹ́ tí ó ń ṣe kòkárí òṣèlú àti ìdàgbàsókè ilẹ̀ Yorùbá lápapọ̀. Ó kọ̀wé fipò adarí Afẹ́nifẹ́re sílẹ̀ lọ́dún 2015.[2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Awon Ìtọ́ka sí
- ↑ Àdàkọ:Cite wetitle=An oldman in need of a birthday gift - Nigeria and World News
- ↑ Johnson, Dayo (2015-11-01). "Pa Fasoranti resigns as Afenifere leader, says goals were eroded". Vanguard Nigeria. Retrieved 2019-10-04.