Richard Dreyfuss

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Richard Dreyfuss jẹ́ òṣèré tó gba Ẹ̀bùn Akádẹ́mì fún Òṣeré Okùnrin tódára jùlọ ní ọdún 1977 fún eré 'Goodbye Girls'. Wọ́n tún yàn án ní ọdún 1995 fún àmì "Mr Holland's Opus".[1]

Richard Dreyfuss
Richard Dreyfuss Cannes 2013.jpg
Ọjọ́ìbíRichard Stephen Dreyfus
Oṣù Kẹ̀wá 29, 1947 (1947-10-29) (ọmọ ọdún 75)
Brooklyn, New York, U.S.
IbùgbéEncinitas, California, U.S.
Iṣẹ́Actor
Ìgbà iṣẹ́1964–present
Olólùfẹ́
  • Jeramie Rain
    (m. 1983; div. 1995)
  • Janelle Lacey
    (m. 1999; div. 2005)
  • Svetlana Erokhin
    (m. 2006)
Àwọn ọmọ3 (with Rain)
Àwọn olùbátanÀwọn Ìtọ́ka síÀtúnṣe

  1. "eOnline Profile". Archived from the original on 2008-01-01.