Richard E. Taylor
Richard Edward Taylor, CC, FRS, FRSC (ojoibi November 2, 1929 ni Medicine Hat, Alberta) je ojogbon omo Kanada-Amerika ni Yunifasitu Stanford.[1] Ni 1990, o pin Ebun Nobel ninu Fisiksi pelu Jerome Friedman ati Henry Kendall "fun iwadi asiwaju won nipa fifankiri awon elektroni lori protoni ati neutroni, to se pataki fun idagbasoke afijuwe quark ninu fisiksi atasere."[2]
Richard Edward Taylor | |
---|---|
Ìbí | 2 Oṣù Kọkànlá 1929 Medicine Hat, Alberta |
Pápá | Particle physics |
Ilé-ẹ̀kọ́ | SLAC LBL École Normale Supérieure |
Ibi ẹ̀kọ́ | Stanford University of Alberta |
Doctoral advisor | Robert F. Mozley |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Nobel Prize in Physics (1990) |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |