Dick Tiger

(Àtúnjúwe láti Richard Ihetu)

Dick Tiger (orúkọ àbísọ Richard Ihetu; August 14, 1929 – December 14, 1971) jẹ́ ajẹ̀sẹ́ tó gba World Middleweight àti World Light Heavyweight Championships.[1]

Dick Tiger
Dick Tiger (left) with Nino Benvenuti in 1969
Statistics
Real nameRichard Ihetu
Rated at
Height5 ft 8 in (1.73 m)
Reach71 in (180 cm)
Birth date(1929-08-14)Oṣù Kẹjọ 14, 1929
Birth placeAmaigbo, Colony of Nigeria
Death dateDecember 14, 1971(1971-12-14) (ọmọ ọdún 42)
Death placeAba, Nigeria
StanceOrthodox
Boxing record
Total fights82
Wins60
Wins by KO27
Losses19
Draws3

Tiger kó lọ sí Liverpool, ní Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì láti lọ ṣiṣẹ́ ìjẹ̀sẹ́, àt'ibẹ̀ ló ti kó lọ sí Amẹ́ríkà.

Wọ́n fi orúkọ Tiger sínú Ilé Olókìkí Ìjẹ̀sẹ́ Àgbáyé ní 1991. Ìwé-ìròyìn The Ring pèé ní Fighter of the Year (Ajẹ̀sẹ́ Ọdún) ní 1962 àti 1965, bẹ́ẹ̀sìni Boxing Writers Association of America (Ẹgbẹ́ Oníròyìn Ìjẹ̀sẹ́ Amẹ́ríkà) pèé ní Fighter of the Year (Ajẹ̀sẹ́ Ọdún) ní 1962 àti 1966. Ní 2002, Ìwé-ìròyìn The Ring dìbò fún Tiger ní ipò 31k bíi ajẹ̀sẹ́ olókìkí jùlọ lágbàáyé.[2]

Tiger jẹ́ ọmọ ẹ̀yà Ígbò, ó sì jà bíi sójà fún Biafra nígbà Ogun Abẹ́lé Nàìjíríà.[3]

  1. "The Lineal Boxing World Champions". The Cyber Boxing Zone Encyclopedia. Retrieved November 6, 2016. 
  2. Andrew Eisele. "Ring Magazine's 80 Best Fighters of the Last 80 Years". About.com Sports. 
  3. Rogak, Larry (2005). You Don't Know Dick!: An Onomastic Reference Compendium. iUniverse. p. 80. ISBN 0-595-35433-5. https://books.google.com/books?id=2El5T0q86GcC&pg=PA80.