Richard Moguena
Richard Moguena, ti a bi ni ọjọ kinni Oṣu Kẹsan, ọdun 1986, jẹ oṣere bọọlu inu agbọn alamọdaju ọmọ orilẹ-ede Chad. Lọwọlọwọ o ngba fun AS Africana ti D1 Chad .
O ṣe aṣoju ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede Chad ni 2011 FIBA Africa Championship ni Antananarivo, Madagascar, nibiti o ti jẹ atungba ti o dara julọ ti ẹgbẹ rẹ ati eniti o mo bọọlu ofe ju. [1]
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ Chad accumulated statistics | 2011 FIBA Africa Championship Archived 2016-02-01 at the Wayback Machine., FIBA.com, accessed 11 January 2016.